Feed Blog Circles Pages Dashboard
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Circle Create Page
O

Odi Okanran

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
44 views Updated Oct 28, 2026 fafore.com/odu/odi-okanran
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa ni ki elelyi orubo isegun
pe ogun kan ni owole to eleyi
EBO ni kose kola ba segun
kio si lo fi ewure kan bo
ifa

Ese — Yoruba Verse

Idin ranhinrahin
Idin kotokoto
Adifafun oju ti lonu egungun lojoko
Ewe aminsinminsin itafun pelu erun osun ao wa lopo ao wa mon fi oyin lo larolaro.
MEDICINE

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Eran ewure kan
  • Epo
  • Eko
  • Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ase — Ifa Spiritual Message

ifa sope ki elelyi orubo ajinde
ko si lobo ogun agede pelu
eyele meji kio si fi akuko adire meji rubo

Ese — Yoruba Verse

Idin ranhinranhin
Baba lawo oyin
Losefafun oyin
Igba ti momi oju sogbere ire gbogbo

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Akuko adire meji
  • Eyele meji
  • Epo
  • Eko
  • Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa pe oun pe ire fun omo iya meji kiwon orubo ola kiwon ole ba la ki won osilo fi ewure bo ifa

Ese — Yoruba Verse

Idin ni gbapa
Olokanran ni gbese
Eni totele debi oku oloro
Ni yio sa ohun rere gbe
Adifafun orunmila
Baba lole sinku adete laibaku

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Eran ewure kan
  • Epo
  • Eko
  • Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa sope oun pe ire iyin fun eleyi pe ibikan ni elelyi loyin ebo ni kose ko leba ni yin loun kio si lota onilu lore

Ese — Yoruba Verse

Idinrahinranhin
Awo omi
Lose fafun omi
Igba ti be lagba temon omo araye

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Akuko adire meji
  • Epo
  • Eko
  • Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ao toju awo ilu pelu ewe
anu ao wa gun po mon
ose dudu ao wa fi omi
agbon po ao wa mon fiwe
larolaro

Isegun — Alchemist Formula

Yoruba

ao ju eya ogun tise oku
ta toba ya kuro lara eyin
ti won mon fi lu irin legbede
ni ao mu pelu ewe segun sete ao wa lopo ao wad a sinu epo pupa ao wa mon la lalale

Videos

Watch Odi Okanran teachings on our channel.

Explore Ifa

Odi Okanran is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Odi Meji, Odi Ogbe, Odi Oyeku, Odi Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Odi Okanran Odu.