The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ase — Ifa Spiritual Message
Ese — Yoruba Verse
Lopelope kari baba rere bini lomon
Adifa fun orunmila
Ifa bi fagbemi sile
Ifa o bi fagbemi soko
Ebo ni won ni baba ose
O si gbebo ni be orubo
Nje esaje ajodi mon
Gbogbo wa lope o jo gbe
Esa je ajodi mon
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Akuko adire meji
- Eyele kan
- Epo
- Eko
- Obi
Ase — Ifa Spiritual Message
Ese — Yoruba Verse
Ki emi naa o kase fun o
Adifafun onika mogun
Omo arakika kawo iku ko
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo ni be o rubo
Nje, kini o bami kawo ota ko
Akika kosai bani kawo ota ko
Akika.
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Eran akinka meji
- Epo
- Eko
- Obi
- Oti
Ase — Ifa Spiritual Message
Ese — Yoruba Verse
Okanjua agba ni n woke radi radi
Ejo ni o komo ti e leyin yoyo kari oko
Adifa fun kerenulesin
Eyi ti yoo gboo gboo
Eyi ti yoo too too
Eyi ti yoo lo egberindinlogun laye
Ebo ni won ni ko se
O si gbe ebo nibe o rubo
Nje bi mi kasai legberun odun laye motidi kerenulesin.
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Akuko adire kan
- Okete aye kan
- Epo
- Eko
- Obi
Ase — Ifa Spiritual Message
Ese — Yoruba Verse
Adifa fun ode
Ti n sode re gboje eluju je
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe o rubo
Nje erekinsin nibon n wii
Eni o mogun emon mon dale
Ere kisin ni bon wii.
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Eyele merin
- Akuko adie kan
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Isegun — Alchemist Formula
Yoruba
Explore Ifa
Ika Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ikameji. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Ika Ogbe, Ika Oyeku, Ika Iwori, Ika Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ika Meji Odu.
