Feed Blog Circles Pages Dashboard
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Circle Create Page
I

Irete Ose

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ifa Irete Ose
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
43 views Updated Oct 27, 2026 fafore.com/odu/irete-ose
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Irete Ose

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ase — Ifa Spiritual Message

Ibi kan lele yii nlo yii, ko rubo awon ota po loun, yio si segun won ko gbebo, pe aala oorun ti eleyi sun ko dara rara apeere awon ota ni, won o si fe pa eleyi ni.

Ese — Yoruba Verse

Ogbologbo Oya ni yipon eyin
Adifafun orunmila
Baba n sawo relu ilodi

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Epo
  • Eko
  • Agbado
  • Akuko adie kan
  • Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ase — Ifa Spiritual Message

Keleyi orubo bi kan leleyi n loyii, ogunpo nibe sugbon keleyi o rubo paa paa julo, won ti fi oogun soju ona fun eleyi, nibi ti eleyi ba gbalo ko maa gbabe bo nitori awon ota ti yan le kalefun.

Ese — Yoruba Verse

Pa man siki
Adifafun boti
Ti n gbogun lo ilu ajarun

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Epo
  • Eko
  • Agbado
  • Opolopo okababa
  • Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ase — Ifa Spiritual Message

Keleyi orubo, eleyi n sukun aje, ifa ni ire aje n bo fun eleyi gbogbo oun ti eleyi se kolojutu lenu isere kolojuto keleyi o dimo n ifa, lodo ifa nire aje re wa kosi ma maa safojudi.

Ese — Yoruba Verse

Yoo yo biyoyo
Yoyo bi yoyo
Adifafun won ni rete alaje
Nibi won ti n sukun aje suru suru

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Epo
  • Eko
  • Agbado lopo lopo
  • Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ase — Ifa Spiritual Message

Keleyi orubo ire aje gidi gidi fun eleyi, ki eleyi o fi elede bofa kara o le defun a je eleyi yio si ma n eeyan Pataki Pataki lara awon eeyan Pataki yii ni eleyi yioti la

Ese — Yoruba Verse

Ifa see ko awo omode
Eniyan atata se mo
Awo oke ijero
Aimo eeyan atata ka so wipe a o lowo lowo
Apata piti oruko ni won fi ma n ni
Adifafun won ni rete alaje
Nibi ti won ti n wa owo piti piti

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Epo
  • Eko
  • Agbado
  • Owo
  • Elede a o fi bofa

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN
Ewe tete ewerinrin odundun ire lapa lapa ewe igba ewe gure a o gbo gbogbore po a o fi we ifa a o pa agbegbo adie bofa ati eku eja omin ti afi wefa yi a o fiwe a o man yo mu.

Videos

Watch Irete Ose teachings on our channel.

Explore Ifa

Irete Ose is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ifa Irete Ose. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Irete Meji, Irete Ogbe, Irete Oyeku, Irete Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Irete Ose Odu.