The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ase — Ifa Spiritual Message
Ese — Yoruba Verse
Eni aja bawa laja balo
Adifa fun Orunmila
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe o rubo
Nijo ti baba o teju mo akapo re ginringinrin
Nje ifa teju momi o wo mi ree,
Eji koko Iwori
To bateju mon ni awon ni ri re gba,
Eji koko Iwori
ifa teju mo mi o womi ree
Eji koko Iwori
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Eku meji
- Eja meji
- Abodie meji
- Epo
- Eko
- Obi
Ase — Ifa Spiritual Message
Ese — Yoruba Verse
Oku subu lagba
Adifa fun soreyo
Ti n momi oju sogbere omo
Ebo ni won ni kose
O gbebo nibe o rubo
Nje e wole ayo ewomo
A kii bale ayo laikun
E wole ayo ewo omo
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Ewure Kan
- Epo
- Eko
- Obi
- Owo
Ase — Ifa Spiritual Message
Ese — Yoruba Verse
Adifa fun alahuntakun
Ti yo ma soohun gbogbo bidan bidan
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo ni be o rubo
Nje bidan bidan ni mo se nire aye temi loni o
Moti dogodo gboke odo payin keke soloko
Alatankun iwo losohun gbogbo bidan ni mose nire gbobgo
temi loni o
Mo ti dogodo gboke payin keke soloko
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Eye etu kan
- Epo
- Eko
- Obi
- Owo
Ase — Ifa Spiritual Message
Ese — Yoruba Verse
Oloda omon kin ode labokore
Komon raunro peti
Adifafun ode gbahunsasa
Ti sunkun pe oun koni eni kan
Ebo ni won ni ko se
O gbebo nibe orubo
Nje ode gbajo o
Ode gbahunsasa ode deleni
Ode gbahunsasa
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Eku kan
- Eja kan
- Abodie kan
- Epo
- Eyin
- Obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Isegun — Alchemist Formula
Yoruba
Explore Ifa
Iwori Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Iwori Meji Kinni. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Iwori Ogbe, Iwori Oyeku, Iwori Odi, Iwori Irosun.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Iwori Meji Odu.
