Feed Blog Circles Pages Dashboard
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Circle Create Page
O

Obara Oyeku

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Obara Yeku
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
47 views Updated Oct 28, 2026 fafore.com/odu/obara-oyeku
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Obara Yeku

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ase — Ifa Spiritual Message

ifa pe ki elelyi omon
se ase ju lodo eni ti notju re
pelu gbogbo nkan ti won nse fun
ifa pe ti oba ti ni aseju
yio pada si eni ete ni

Ese — Yoruba Verse

ESE IKINI
Atare lose nu jinkun
Ora kan nikun atare
Adifafun esu legbe tise egbon monrari
Igbati won nroko allero odun

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Eja ajabo meji
  • Ki won oti bori won
  • Okete fi awon agbalagba
  • Epo ati eko
  • Akuko adie meji lebo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Obara oyeku
Yeku yeku yekete
Adifafun odan
Odan nsawo losi ojuode
3
Ese Keta
Ese Keta

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa pe lara omo iya
eleyi ni oore re wa ko mon
se afojudi soro ebi rara

Ese — Yoruba Verse

Apa aja
Itan esin
Okere si nkanti agbalagba
Mon pede lelori
Adifafun olobara ti nsawo
Lo sile oyeku egbon re

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Pepeye Meji
  • Eyele meji lako ati labo
  • Epo
  • Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Obara oyeku
Eeru ko eru louin osin oba
Iworiko oloun osinm ogba mon
Obinrin ko oloun ogba oorun oka
Oun mon
Adifafun bereri tise
Aya agboniregun
Ebo niwon ni kose
O si gbebo n ibe o rubo
Nje obara oyeku ta logbobeeri

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ewe saworo pepe topo dada, ao lo a o fise igbin meji, lepo niyo aote iyere osun ni obara oyeku afise ifa naje, aose adure si aokoje

Isegun — Alchemist Formula

Yoruba

ewe eye aje obale mesan fun okunrin meje fun obinrin 7 eyo atare 9 mesan fun okunrin, eyo atare 7 meje fun obinrin, ori e eku emon ti won fi rubo won olopapo ao fi sin gbere si aarin ori lati iwaju de ipako
MEDICINE

Videos

Watch Obara Oyeku teachings on our channel.

Explore Ifa

Obara Oyeku is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Obara Yeku. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Obara Meji, Obara Ogbe, Obara Iwori, Obara Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Obara Oyeku Odu.