Feed Blog Circles Pages Dashboard
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Circle Create Page
Odi Meji

Odi Meji

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Odinmeji
Odu Ifa BODE Oracle 3 Languages Sacred Pattern
Listen
92 views Updated Oct 28, 2026 fafore.com/odu/odi-meji
Read in: English Yoruba Español Português Français Chinese Russian German Arabic
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Odinmeji

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa ni ki eleyii o rubo nitori ire gbogbo, pe oju ire gbogbo ni pon eleyi, ebo ire gbogbo ni koru kole ba ni ire gbogbo.

Ese — Yoruba Verse

Odinmejeji loto lowa re joko
adifafun Onibode ajegbere mogun
Igba ti momi ojusogbere ire gbobgo
Ebo ni won ni kose
O si gbebo nibe orubo
Nje ire gbobgo poro ni bode
Ni bode ni ile aje
Ire gbogbo poro ni bode
Ni bode ni le ire gbogbo

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Pepeye Meji
  • Akuko kan
  • Epo
  • Eko
  • Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa nipe ki eleyi o rubo, Ifa pe ire fun onitohun lopo lopo. Ifa ni ohun gbogbo toni tohun ba n fe ko mon se ko lati bere lowo ifa ki ire o lede fun.

Ese — Yoruba Verse

Itaruku lawo itaruku
Itaruku lawo itaruku
Adifafun igba
Ti n sawo rode oyo
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe orubo
Nje igba oyo nile o
Igba emi lowa de ni oko.

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Agbado
  • Ewa
  • Isu
  • Oruko kan
  • Epo
  • Eko
  • Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa ni ohun pe ire omo fun eleyi pe oju omo ni pon eleyii, ifa pe koru bo omo kio si mon ko egbin kole ba bi mo.

Ese — Yoruba Verse

Asahunkulu monkulu moyin baba
Adifa fun idin ati igogo
Ni ojo tiwon lole kan rile omo ni bibi
Ebo ni won ni ki won ose
Won si gbebo nibe won rubo
Nje, ewole ayo e womo
A kii bale ayo laikun
E wo le ayo ewo mo.

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Aran elede odidi kan
  • Epo
  • Eko
  • Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa ni ki eleyi o rubo emi re, ifa pee ori re yio gbe, emi re yio gun, sugbon ebo ni kose dara dara.

Ese — Yoruba Verse

Kákólé bíri kòtò fòòsà
Bòòsà o gba bí Òrìṣà o gba kò ree gbé reesáké
Kò rọ̀ dàn lókùn kòrí bí agbára ẹ̀bí ṣe dá wọn
Adífá fún Asákẹ́ tise ọmọ Ògún
Àbù fún Arúmọn tise ọmọ ìjà
Adífá fún Odì náà tí s’ọmọ bíbí inú Agbónmìrègún
Ebo ni won ni ki won ose
Won gbebo nibe won rubo
Nje odi naa di naa ibi obati naa man kun
Kodinaa maru odi naa di naa bi.

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Eran Agbo kan
  • Epo
  • Eku
  • Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ao toju agbado ati okababa ati ewa ati ewe ato ao wa jo po ao wa mon fi fo eko mun tabi ka fi oyin lo, ekan lojumo.

Isegun — Alchemist Formula

Yoruba

Ewe imon ewe apada ewe dandan ao gun meteta po mon ose dudu ao mon fi we fun ojo mesan tobaje okunrin, tobaje obinrin ojo meje ni yio fi we.

Videos

Watch Odi Meji teachings on our channel.

Explore Ifa

Odi Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Odinmeji. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Odi Ogbe, Odi Oyeku, Odi Iwori, Odi Irosun.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Odi Meji Odu.