O
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa ni oun pere isegun ki elelyi o lo fin ewa pete pese fun awon agba ko si fi eku eja abodie bofa
Ese — Yoruba Verse
Okanran roro ibeje
Adifafun orunmila
Baba ofi ikoko pete segun otare
Adifafun orunmila
Baba ofi ikoko pete segun otare
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Eku kan
- Eja kan
- Abodire kan
- Epo
- Eko
- Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa peire oye fun eleyi ki elleyi orubo kole badi eni ni nla ko lobo sango pelu agbo
Ese — Yoruba Verse
Okanran Roro Beje
Adifafun sango eyin tiyio je Oba laye
Eyin ti yio je orisa lalade Orun
Adifafun sango eyin tiyio je Oba laye
Eyin ti yio je orisa lalade Orun
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Eran agbo kan
- Orogbo
- Epo
- Eko
- Obi
3
Ese Keta
Ese Keta
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa pe oun pe ire laiku fun eleyi ki eleyi olobo ifa pelu eku meji eja meji abo adire meji
Ese — Yoruba Verse
Gindan gindan loyele
Ijagidingindin loye de
Aso lololo ipako losebo beni koribu sebo
Adifafun orunmila babalole fe
Asaka omi ogun
Nlole f fe arumon omo ija
Nlole e dakegboro omo ososi
Ijagidingindin loye de
Aso lololo ipako losebo beni koribu sebo
Adifafun orunmila babalole fe
Asaka omi ogun
Nlole f fe arumon omo ija
Nlole e dakegboro omo ososi
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Eku meji
- Eja meji
- Abodie meji
- Epo
- Eko
- Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa ni ki eleyi orubo ise gun pe ogun kan loyin elelyi kayi ebo ni ko se kio si lobo ogun pe lu pepeye kio si fi akuko kan rubo fesu
Ese — Yoruba Verse
Okanran rusurusu
Adifafun erinlelojo erun nijo
Ti swon tode orubo waye
Adifafun erinlelojo erun nijo
Ti swon tode orubo waye
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Akuko adire kan
- Pepeye kan
- Epo
- Eko
- Obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ao toju ewe areyin
kosu pelu iyere ao wa fin se
eyele kan je lepo niyo ao
wa se adure si daradara
ao wa je obe naa
kosu pelu iyere ao wa fin se
eyele kan je lepo niyo ao
wa se adure si daradara
ao wa je obe naa
Isegun — Alchemist Formula
Yoruba
Ao toju okiti ogan ao toju aran afe ao wa lo meji ji papo ao wa po mon ose dudu ao wa fi we lale fun ojo meje
Explore Ifa
Okanran Irosun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Okanran Meji, Okanran Ogbe, Okanran Oyeku, Okanran Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Okanran Irosun Odu.
