The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ase — Ifa Spiritual Message
Leleyi wa korrubo
Kole baasegun
Ese — Yoruba Verse
Iwori n wode
Adifa faja tiisomo
Iya ofafa
Igba tinbe laarin ota
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Epo
- Eko
- Akuko die kan
- Agbado
- Owo.
Ase — Ifa Spiritual Message
Gangan lotare
Korubo yio segun re
Ese — Yoruba Verse
Adifafun baayanrin
Tinbe laarin otaa
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Akukodie kan
- Ao fib o baayan rin
- Pelu obi meji
- Epo, eko, agbado, owo.
Ase — Ifa Spiritual Message
Fun eleyi lati okeere
Korubo kole baate lowo
Ese — Yoruba Verse
Iwori n wode
Adifafaje oun Omo
Won tode orubo
Bowaye
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Epo
- Eko
- Agbado
- Owo.
Ase — Ifa Spiritual Message
Eleyi komanbo
Orisa kire ajere oleetelowo
Ese — Yoruba Verse
Adifa fabajo
Tii somo orisa owujin
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Ao fi igbin merin
- bo orisa ati obi meji
- Epo, Eko, Agbado, Owo.
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe owu akese
Aidan
Ao gun po manran won
Ao po po man ose
Ao ma fi we
Explore Ifa
Osa Iwori is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Osa Iwori. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Osa Meji, Osa Ogbe, Osa Oyeku, Osa Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Osa Iwori Odu.
