O
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa ni ki eleyii o rubo pe laarin ota ni o wa, paa paa enin o munle ti eleyii, ota eleyii ni ko sora fun un
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni ngbo moni iwo
Adifafun oninu ire
Ti won o mon gba awin ika le de
Adifafun oninu ire
Ti won o mon gba awin ika le de
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Akuko adie kan
- Epo
- Eko
- Agbado
- Owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa ni ki eleyii o rubo ota, pe ota po fun eleyii ti won si juulo, pe yoo segun won.
Ese — Yoruba Verse
Ose oniwo kiki ogun
Adifafun orunmila
Baba nsawo lo ilu ilawo
Adifafun orunmila
Baba nsawo lo ilu ilawo
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Akuko
- Asa meji
- Epo
- Eko
- Agbado
- Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa pe ki eleyii o rubo, pe yoo la, ola naa yoo po titi po lopolopo, sugbon ebo ni ko se
Ese — Yoruba Verse
Ose wonrin wonrin
Wonhun kankan
Adifafun won lode Ilawo
Nibi ti wonti nkuwo bi eni ti nku elubo
Nibi ti won ti nsa igede
Bi eni ti nsa oogun
Wonhun kankan
Adifafun won lode Ilawo
Nibi ti wonti nkuwo bi eni ti nku elubo
Nibi ti won ti nsa igede
Bi eni ti nsa oogun
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Abodie meji
- Igbin meji
- Epo
- Eko
- Agbado
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa pe ki eleyii o rubo ire, pe ire n bo fun un lati okere pe ebo ni ko maa ru ki ire naa o le tet tee lowo.
Ese — Yoruba Verse
Ose wonran wonon
Adifafun aje
Aje ntorun bow a saye
Adifafun aje
Aje ntorun bow a saye
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Igbin meji
- Abodie meji
- Eyele meji
- Epo
- Eko
- Agbado
- Opolopo owo
Explore Ifa
Ose Owonrin is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ose Meji, Ose Ogbe, Ose Oyeku, Ose Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ose Owonrin Odu.
