Feed Blog Circles Pages Dashboard
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Circle Create Page
O

Otura Owonrin

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Otua Owonrin
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
55 views Updated Oct 26, 2026 fafore.com/odu/otura-owonrin
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Otua Owonrin

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa pere fun eni toda ifayi ifa pe ibi kan leleyi wa tin gbe si se korubo ki ola o le bade fun nibe ko sib o fa dada

Ese — Yoruba Verse

Karojoye
Kabebejoye
Obaba nba orobenikan moyo osooro kun lawo eti opon Adifafun ojolugogogo
Tii se akora eru elerigi tesi

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Eyele
  • Akuko adie
  • Agbebo adie
  • Eye Etu
  • Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa pere fun eni toda ifayi ifa ni won bu eleyi pe o le ifa ni awon ebire ati awon orere won foju pe kole dafun wo ko rubo ko sib o ifa dada ko si mo ba yan ja rara

Ese — Yoruba Verse

Ewe le olele le
Ole mi alelee le wure
Adifafun orunmila
Baba o lele le gbogbo ebi re o ko

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Akuko adie
  • Agbebo adie
  • Eyele
  • Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa pere fun e ni toda ifa yi korubo ire gbogbo ifani ko si eni tole feyin ko si alanu fun ifa ni oun ni ko mo fo gbogbo ororele lowo ko ma fi opolopo amola bofa

Ese — Yoruba Verse

Toro toki
Adi fafun alamola ketu
Igba tin momi oju sogbere ire

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Akuko adie
  • Agbebo adie
  • Eyele
  • Igbin
  • Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa pere fun eni toda ifayi ifa ni ko rubo ki o leba mo gba iyii ifa si ni oun pere omo fun eleyi

Ese — Yoruba Verse

Ewe le olelele ole mi ale lelewure
Adifafun eegungun
Ti n toroun bowaye

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Agbebo adie
  • Akuko adie
  • Eyele
  • Opolopo owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ewe akisan ewe ire ewe omini ewe oju saju ao lo ao fi se eran elede ti a ge si merindinlogun lepo niyo ao ko abaa meji si ti o bajina ao so ao ma fi abayimuje ti aba ti jetan ao ko abaa yi si ori esu tabi orifa

Isegun — Alchemist Formula

Yoruba

Egbo legun oko pupo ao jomo odidi atare kana o fi sin gbere yipo orun owo mejeji

Videos

Watch Otura Owonrin teachings on our channel.

Explore Ifa

Otura Owonrin is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Otua Owonrin. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Otura Meji, Otura Ogbe, Otura Oyeku, Otura Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Otura Owonrin Odu.