Feed Blog Circles Pages Dashboard
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Circle Create Page
O

Owonrin Ogbe

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
32 views Updated Oct 28, 2026 fafore.com/odu/owonrin-ogbe
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa ni eni yii pelu enikan jo n sowo po, pe ebo ni ko ru komani ota re ni ko fe ki eleyii o sorire, sugbon eleyii yoo sorire, ebo ni ki o se

Ese — Yoruba Verse

Osemin masesan
Adire damin loogun
N o foleyin
Adifafun alabahun toun Orunmila jo n sota

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Eku meji
  • Eja meji
  • Abodie kan
  • Akuko adie kan
  • Epo
  • Eko
  • Agbado
  • Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa ni ke eleyii o rubo pe aarin ota ni eleyii wa, pe ko rubo oun yoo gba eleyii sile lowo awon ota re.

Ese — Yoruba Verse

Ibi lebelebe eti aso leema wa
Adifafun yeepe
Ti yoo gbara re ti yoo gbagi oko

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Ewe yeepe lopolopo
  • Akuko adie kan
  • Epo
  • Eko
  • Maiz
  • Opolopo owo.
3
Ese Keta
Ese Keta

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa ni ki eleyii o rubo pe yoo la ti okiki re yoo si kan kaa kiri gbogbo aye.

Ese — Yoruba Verse

Pabutu yeke
Adifafun jesu
Ti n tode orun bow aye

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Amala ati obe ohunla
  • Eku meji
  • Eja meji
  • Obi meji
  • Oti
  • Eyele meji
  • Epo
  • Eko ati Agbado
  • Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa ni aje n bo fun eleyii lenu ise re, pe eleyii yoo la ti gbogbo aye yoo si mo on.

Ese — Yoruba Verse

Pabutu yeke okun kan leru
Adifafun Aje
Igba ti n tode orun bo wa sile aye

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Igba olomori kan
  • Akuko adie kan
  • Epo
  • Eko agbado
  • Owo.

Videos

Watch Owonrin Ogbe teachings on our channel.

Explore Ifa

Owonrin Ogbe is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Owonrin Meji, Owonrin Oyeku, Owonrin Iwori, Owonrin Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Owonrin Ogbe Odu.