O
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa ni ki eleyii o soro pe ota nla kan ree fun eleyii, ota yii ju eleyii lo, pe korubo ko si ma jaya pe yoo segun eni naa
Ese — Yoruba Verse
Igi nla yoninju
Ojue tole kokoko
Adifafun eegun abufun euru
Igba ti won jo n sota
Ojue tole kokoko
Adifafun eegun abufun euru
Igba ti won jo n sota
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Ekuru funfun
- Eyele funfun meji
- Abo adie
- Eku meji
- Eja meji
- Epo pupa
- Eko
- Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa ni keleyii o rubo pe won o fi eleyii se olori kan nibe pe ibe si ni eleyii yoo ti di olola laye re.
Ese — Yoruba Verse
Pamansiki adifafun boti
Ti n gbogun lo ilu ajarun
Oyeku rusu rusu
Adifafun won legba eesu
Nibi won ti nkori aje jo
Ti n gbogun lo ilu ajarun
Oyeku rusu rusu
Adifafun won legba eesu
Nibi won ti nkori aje jo
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Opolopo oka baba
- Akuko adire kan
- Epo pupa
- Eko
- Agbado
- Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Oyengbosun
Adifafun aje oun omo
Won jija agba nile Olodumare
Adifafun aje oun omo
Won jija agba nile Olodumare
Explore Ifa
Oyeku Irosun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Oyeku Meji, Oyeku Ogbe, Oyeku Iwori, Oyeku Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Oyeku Irosun Odu.
