O
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa ni ki eleyii o maa ja si ogun ki o ma je pe ibi ogun yii ni eleyii yoo ku si, pe won yoo pee si oro ile kan sugbon ki o ma da si oro naa rara.
Ese — Yoruba Verse
Olowo ni n fa oko olofa aferu
Iwo o raala
Emiin o rala
Aroko man rala lodija sile
Adifafun oyeku okanran
Igba ti won n be laarin ota
Iwo o raala
Emiin o rala
Aroko man rala lodija sile
Adifafun oyeku okanran
Igba ti won n be laarin ota
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Oko iroko kan
- Akuko adire kan
- Epo eko
- Agbado ati Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa ni ore eleyii kan niyii ti yoo ta eleyii nijanba, pe ki eleyii o sora fun un ore naa daa daa kosi paaro aye ibi ti n sun, ko ma sun ibe fun odidi ojo meje.
Ese — Yoruba Verse
Oyeku olokanran kan Babalawo
Awo lodifafun awo tii sore oman
Awo lodifafun awo tii sore oman
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Aso eni yii ti o ni awo meta
- Epo
- Eko
- Agbado
- Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa ni ire eleyii ti silo sugbon korubo pe ire re n pada bow a joko ti pada
Ese — Yoruba Verse
Atawin opele awo won niragbiji
Adifafun won niragbiji
Nijo ire won n silo
Adifafun won niragbiji
Nijo ire won n silo
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Alabahun kan
- Akuko adire kan
- Epo pupa
- Agbado
- Opolopo owo
- Omo agbara to n san
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa ni eleyii yoo la, pe ko si rubo fun iyawo re naa nitori
won yoo jo la lasiko kan naa ni
won yoo jo la lasiko kan naa ni
Ese — Yoruba Verse
Gbongbo sigila awo ile alase
Adifafun Alaase abu fayare
Adifafun Alaase abu fayare
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Ako pepeye kan
- Epo pupa
- Eko
- Agbado
- Opolopo owo.
Explore Ifa
Oyeku Okanran is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Oyeku Meji, Oyeku Ogbe, Oyeku Iwori, Oyeku Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Oyeku Okanran Odu.
