Feed Blog Circles Pages Dashboard
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Circle Create Page
I

Irosun Iwori

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
55 views Updated Oct 28, 2026 fafore.com/odu/irosun-iwori
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa loun pe re fun eleyi ko gbobe egbe re dada ifa loun ogbe elelyi keleyi o mun ra si ebo ruru ati ifa egbe wipe iyanju eleyi ko kun to
Ifa ni ki eleyi lo re bo orisa orisa kan wa ni idile awon eleyi ki won gbe orisa na jade ki won o bo dada ( opolopo igbin obi ati oti )

Ese — Yoruba Verse

Oju odo lodo fi gunyan
Oju awo lawo fi gbobe
Akii foju oloju sowo kajere
Adifa fun Teegbe
Tin somo bi bi inu agbomiregun
Igba ti n torun bo waye

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Aso funfun
  • Eyele
  • Eyin
  • Opolopo owo
  • Akuko adie
  • Opolopo igbin
  • Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa pere fun eni to da ifa yi ifa ni oju omo nipon eleyi ifa ni omun eleyi bi tobi ju kan lo ifa ni eleyi bi abiku pe o ifa so pe omun ka omo to ba je korubo ki won o bo omunyan

Ese — Yoruba Verse

Bola banta owuwon
Bola badijude asuwon
Akoyinsi ola osunhan
Won ti jo jingindinringin lojudebaba enikan ri koto wu gbeegi
Adifafun orisanla oseremogbo
Ti yo mo rata baye
Ahoro ile aboju poki
Adifa fun olomu jugba
Ti n se yeye ere
Igba ti n momi oju sogbere omo

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Abo adire
  • Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

O fi tiele gbo teni eleni
Adifa fun emilenige
Tii sawo rode awote
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa pere fun eni to da ifa ko rubo ifa ni ti won pe eleyi ni bi kan ko tete mo debe tori ire ni

Ese — Yoruba Verse

ESE IFA
O fi tiele gbo teni eleni
Adifa fun emilenige
Tii sawo rode awote
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe o rubo
Nje emilengbe o de Arode
Awoye gbogbo la bare nle mode awuro

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Eyele
  • Akuko
  • Opolopo owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ewe ina ao lopo mo iyere (16)ao fi se edo maalu tia ge simerindinlogun (16)leponiyo ao je ni gbibgo nan

Isegun — Alchemist Formula

Yoruba

Awo etu de egun ori ewure ti won fib o ifa ao jo mo odidi atare kan aofi sin gbere si arin ori meta (3) ni ao sin

Videos

Watch Irosun Iwori teachings on our channel.

Explore Ifa

Irosun Iwori is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Irosun Ogbe, Irosun Oyeku, Irosun Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Irosun Iwori Odu.