Feed Blog Circles Pages Dashboard
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Circle Create Page
I

Irosun Obara

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
46 views Updated Oct 27, 2026 fafore.com/odu/irosun-obara
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa ni oun o ba eleyii segun paa pa julo obinrin ni yoo segun fun eleyii, ebo ni koru , ko lo ree bori iyawo re.

Ese — Yoruba Verse

Won debi
Won dare
Oke ni o diyan ega olayaja bi omo oruko
Adifafun Orunmila
Baba momi oju sogbere ire

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Omo odo meji
  • Iya odo meji
  • Oruko nla meji
  • Opolopo yangan
  • Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa po oun pere fun eni toda ikayi ko rubo nitori arun kofi opolopo abe robo ati aso arare

Ese — Yoruba Verse

Oju monipo
Eniyan moni ofa
Oju to moni kogbodo laimoni mo
Adia fun nini oun salapa
Iyekan okonla abori yebeyebe
Igba ti se ogbogba arun
Ti n nira kaka alaile dide

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Akuko adie
  • Igbaabe
  • Aso arare
  • Opoplopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa pere fun eni toda ifayi ko rubo niti ori ogun ifape ogun kan kan nje eleyi ifa ni oun loun o gba kale lowo ogun na komo di opo ifare mun.

Ese — Yoruba Verse

Agbon nije sibi kando
Irosun lawo ega
Adifda fun iyere ope
Eyi tiko lele mo
Ti n fowo ara mun igi

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Akuko adie
  • Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa pe ire oye fun eni toda ifayio korubo ifa ni won o fije olortio ni bikan

Ese — Yoruba Verse

Ega sususu awo opo komoni
Adifa fun ojiji
Ti won o mun je baale lodo

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Eyele
  • Opolopo owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Eweogo ewe iranje ewe igbo ewe esisi ewe alukerese ao gun po mo ose ao fi lofinda bintu po ao kosi aso funfunti aran ni asunhan ao so kosi oke ko gbodo kanlemo
Eye ega merindinlogun (16) odidi atare kan aojo po ao fisin gbere merindinlogun (16) si ari ori

Videos

Watch Irosun Obara teachings on our channel.

Explore Ifa

Irosun Obara is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Irosun Ogbe, Irosun Oyeku, Irosun Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Irosun Obara Odu.