Feed Blog Circles Pages Dashboard
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Circle Create Page
O

Ofun Obara

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
50 views Updated Oct 28, 2026 fafore.com/odu/ofun-obara
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa pere fun eni to da fayi ki
Eleyi o rubo nuitori ola kosi
Ma kanju ifa ni ola re konipe
Tio fi de

Ese — Yoruba Verse

Ofun bala difafun akanju oola
Adifafun akanju ola

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Eye etu
  • Eyele
  • Eko
  • Epo
  • Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa pere fun eni toda ifayi
Ki eleyi orubo nitori aje
Ifa ni ore kan nbe fun
Eleyi ifa ni won o gbodo yara
Won rara nitori ire ola
Ifa pere fun enitoda fayi k elelyi orubo ifa ni elelyi
Fe ba eni kan toni agbara jai ka ni komo ba eni naa jao

Ese — Yoruba Verse

Aja nio wuko
Akuko adie ni oha Kelenbe gbe mi
Ita gba-n-gba gbangba
Ni solu ware ni pele
Adifafun edun oun iwa
Ti won jo nu rin lailai

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Akuko adie
  • Eyele
  • Pepeye
  • Eko
  • Epo
  • Opolopo owo
  • Igbin
  • Akuko adie
  • Eko
  • Epo
  • Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa pere fun eni toda ifayi ki orubo
Sisegun ifani won nsa
Ogun si elelyi korubo
Ogun tiwon nsa orire nio
Gbado de won situn robi si eleyi
Won o ro oun toda pelu eleyi
Ifa pere fun enitoda fayi
ki elelyi orubo ifa ni oun pe
re omo fun elelyi ika ki
eleyi ko ka oun nje nimun

Ese — Yoruba Verse

Ofun bala olobara bati
Adifafun Onibara
Omo ayeyere ati ogun

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Oruko
  • igbin
  • Eko
  • Epo
  • Opolopo owo
  • Agbebo adie
  • Eku
  • Eja
  • Eko
  • Epo
  • Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa pere omo fun eni tia
Da ifayi fun ifa ni agan kan ni toju omo won ifa aya ifa ni ika sini oma se oge kodi oge sise ku tori kole ba bimo
ifa pere fun enito da ifayi
ki elelyi orubo si eni ise ki
osi fi akuko adie bo esu ifan
omo iya meji ni oun bawi ki
won o rubo sieni won

Ese — Yoruba Verse

Ogbo imodo ni koyin seyin
Adifafun arefun we ti se
Aya agbon niregun

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Agbebo adie
  • Eko
  • Eja
  • Epo
  • Opolopo owo
  • Akuko adie
  • Epo
  • Eko
  • Opolopo owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ao toju ewe oro ewe akisan ao lo ao fi se igbin meri lepo ni yo aowa foju imin ojo ao wa fit e odu ifa fofun olobara ao wa se adurosi ao wa je obe naa ao lobo awon ikarahun igbin yi mon eti odo fibasan
Ao toju ewe ajagun morase ao toju
ewe toto ao toju iyere ao wa bop o ao wa fi se eye etu kan lepo niyo ao w ate iyere osun ni odufa ofin karan ao wa se adura si ao waye obe naa

Isegun — Alchemist Formula

Yoruba

Ao toju awo imondo pelu sewe
Alupayinde ao wa jopa po ao wa po mon ose dudu ao wa fi we fun ojo meje
ao toju ori eye awo ati ori eyele ao toju ewe ori ji ao wa gun gbogbo re papo ao wa po mon ose dudu ao wa mon
fi we laro laro titi ti yio fi tan

Videos

Watch Ofun Obara teachings on our channel.

Explore Ifa

Ofun Obara is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Ofun Ogbe, Ofun Oyeku, Ofun Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ofun Obara Odu.