O
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa pere fun eleyii, ifa ni ki eleyii o rubo pe omo iya eleyii kan re e, ota re gidigidi ni, ki eleyii o rubo ko maa je pe yoo fe e paa.
Ese — Yoruba Verse
Igi nisinyan
Elekun ni sun agbigbo
Reru osa moso
Odidere lodoko
Lobale lose ara jetejete jete
Adifafun orunmila
Ti oun ati ona ilemole jon sota
Elekun ni sun agbigbo
Reru osa moso
Odidere lodoko
Lobale lose ara jetejete jete
Adifafun orunmila
Ti oun ati ona ilemole jon sota
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Igba olomori
- Awo olomori
- Akuko adie kan
- Epo
- Eko
- Agbado
- Owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa ni keleyii o rubo ko le baa segun nitori ota po fun
eleyii.
eleyii.
Ese — Yoruba Verse
Esin ni mawo ona koto koto Koto
Adifafun apan olukoyin
Igba tin fomioju sogbere ire
Adifafun apan olukoyin
Igba tin fomioju sogbere ire
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Oruko Kan
- Obi meji
- Oti
- Akuko adie kan
- Eyele kan
- Epo
- Eko
- agbado
- Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa pe ire fun eleyii, pe ibikan ni eleyii n lo, pe yoo la bo nibe sugbon kogbo ikilo ti won ba n wi fun un.
Ifa pere ola fun eleyii lati okere, pe korubo ki ire ola naa o le too lowo ni kia kia.
Ifa pere ola fun eleyii lati okere, pe korubo ki ire ola naa o le too lowo ni kia kia.
Ese — Yoruba Verse
Mo pe tikun pe tikun
Emi o ri eni wesewese tin difa
Mope eti osa peti osa
Emi o reniyan tutu tin dibo
Adifafun orunmila
Baba o fi arede so binrin
Emi o ri eni wesewese tin difa
Mope eti osa peti osa
Emi o reniyan tutu tin dibo
Adifafun orunmila
Baba o fi arede so binrin
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Igba olomori
- Obe
- Epo
- Agbdo
- Owo
- Eyele funfun meji
- Obi merindinlogun
- Epo
- Eko
- Agbado
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ofun wanrin wanrin
Moja lailo oro n po to
Iyun moja lailo meta la pasi
Moja lailo meta aye
Ti se obinrin ogberi
Adifafun Orunmila
Baba nlo lee gbeye
Tiise obinrin ogberi
Moja lailo oro n po to
Iyun moja lailo meta la pasi
Moja lailo meta aye
Ti se obinrin ogberi
Adifafun Orunmila
Baba nlo lee gbeye
Tiise obinrin ogberi
Explore Ifa
Ofun Owonrin is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Ofun Ogbe, Ofun Oyeku, Ofun Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ofun Owonrin Odu.
