The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ase — Ifa Spiritual Message
Ese — Yoruba Verse
Adifa fun otua
Eyi ti yio ran ahun meji
Ti yio lapere gede
Ebo ni won ni ko se
O gbebo ni be orubo
Nje, otua wo ni
Otua to rahun meji
To la yebe yebe.
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Alabahun meji
- Epo
- Eko
- Obi
Ase — Ifa Spiritual Message
Ese — Yoruba Verse
Adifa fun kekere omo binrin isin
Abu fun agba omon kunrin isin
Igba ti won momi oju sogbere omo
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe won rubo
Nje, atase atato
Afeyin ku e demon ewa lawo lase edomon.
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Abo adire meji
- Eku
- Eja
- Obi
- Epo
- Eko
Ase — Ifa Spiritual Message
Ese — Yoruba Verse
Adifa fun Orunmila
Eleyii ti won o mu je olori abonmonle nife
Igba ti won ni ko rubo aiku fun ara re
O si gbebo nibe o rubo
Nje iku oni pa olori abamonle ni fe
Ajosiki ode awo imonran
Arun ko ni so lori abo monle nife
Ajosikin ode awo imonran.
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Eran oruko kan
- Isu pupo
- Epo
- Eko
- Obi
Ase — Ifa Spiritual Message
Ese — Yoruba Verse
Obi lobi imonran
Emu lemu ara jonjo
Adifa fun keke ke ipapo
Abufun agba gba ipapo
ijo ti won ja sile
Ebo ni won ni ki won o se
Won si gbebo nibe won rubo
Nje kekere ipapo won o se pe lejo
Agba gba ipapo won o se pe lejo
Ifa mo bawon ro
Mon se won
Agbaagba Ipapo Ni won ki ti ejo mo, mo se gun.
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Akuko adire meji
- Eja aro meji
- Epo
- Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Isegun — Alchemist Formula
Yoruba
Explore Ifa
Otura Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Otua Meji. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Otura Ogbe, Otura Oyeku, Otura Iwori, Otura Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Otura Meji Odu.
