Feed Blog Circles Pages Dashboard
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Circle Create Page
Owonrin Meji

Owonrin Meji

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle 3 Languages Sacred Pattern
Listen
53 views Updated Oct 28, 2026 fafore.com/odu/owonrin-meji
Read in: English Yoruba Español Português Français Chinese Russian German Arabic
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa pe ire aje fun eniti odu yi jade fun, ifa ni oju aje nipon onitohun, won ni korubo kole ba laje lowo.

Ese — Yoruba Verse

Owon owo lana won minni
Owon omi lai sun omi
Owon ohunje lape ni yan
Adifa fun ohunyo won
Ti se omo oba leyo ajorin
Igbati momi oju sogbere ire aje surusuru
Ebo ni won ni kose
O gbebo nibe o rubo
Nje esure wa ewa raja omo oba
E po sese wa ewa raja ohunyo won
E sure wa ewa raja omo oba.

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Eku
  • Eja
  • Abodie
  • Akuko
  • Eyele
  • Epo
  • Eko
  • Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa ni ki eleyi o rubo isegun pe awon kan lo gbogun ti eleyi, ifa pe ebo ni ko se ko si mon lo bo ifa dara dara.

Ese — Yoruba Verse

Aragadagba osumonre
Osumonre na ara gadanugba
Adifa fun iroko gbo
Ti n be laarin ota
Ebo ni won ni kose
O si gbebo ni be o rubo
Nje igbo oni di keni mon won
Iroko ara di keni mon won
Iroko ara gadanugba osumare
Osumare naa ara gadanugba.

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Eran ewure kan
  • Epo
  • Eko
  • Obi
  • Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa ni ki eleyi o rubo aiku pe ko fokanbale emi eleyii yoo gun, pe ebo ni ko se.

Ese — Yoruba Verse

Okutannu omi alama seje
Adifa fun owo omo abi marun jere a ruun
Abu fun ese omo marun jere a ruun
Ebo ni won ni ki won o se
Won gbebo ni be won rubo
Nje omo owo kii toju owo ku
Omo ese kito ju ese ku
ifa mon mon je ki toju re rorun.

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Eye etu meji
  • Epo
  • Eko
  • Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa ni ohun pe ire gbogbo fun eniti odu yi jade fun,, Ifa pe ki onitohun o rubo ki o si mo lobo ifa dara dara kole ba lowo lowo.

Ese — Yoruba Verse

Eku sanhin
Eja sanhin
Adifa fun ope eluju
Nijo ti yoo mon rin taje taje
Ebo ni won ni kose
O gbebo ni be o rubo
Nje otogege ki re gbogbo osanmi bo
Mo ti dope eluju
Ara mi lokun
Ara mi laje gbe nso

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Eku
  • Eja
  • Abodie
  • Akuko
  • Eyele

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ileke iyun gidi ti won ti wo dara dara epo opoto ao wagun gbogbore mon ose dudu, eni naa yio maa fi we.

Isegun — Alchemist Formula

Yoruba

A o toju epo iroko ati ewe iroko ati egbo iroko ao wa jopo mon odidi atare kana o wa fi si gbere lari ja ao mon fi iyoku foko mu.

Videos

Watch Owonrin Meji teachings on our channel.

Explore Ifa

Owonrin Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Owonrin Ogbe, Owonrin Oyeku, Owonrin Iwori, Owonrin Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Owonrin Meji Odu.