The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ase — Ifa Spiritual Message
Ese — Yoruba Verse
O fi ihajoko
Adifa fun Lagbanaa
Nijo ti lo le fara so fa lodo ogbe
Ebo ni won ni kose
O gbebo ni be o rubo
Nje yio gbe o o je je bi
Asaigbewon re jeje.
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Eyele funfun meji
- Akuko adire kan
- Epo
- Eko
- Obi
Ase — Ifa Spiritual Message
Ese — Yoruba Verse
Obu yankan yankan loju opon
Adifa fun oloko sa lalu lambi
Omo arigba ota segun
Igba ti n be larin ota
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo ni be o rubo
Nje kini arira fi sete
Igba ota larira fi sete igba ota.
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Eran oruko kan
- Akuko adire kan
- Epo
- Eko
- Obi
- Orogbo
Ase — Ifa Spiritual Message
Ese — Yoruba Verse
Adifa fun Orunmila
Nijo ti lo le gbada lowo orisa
Ti yio fi yomon re lee lowo eleye
Ebo ni won ni kose
O si gbebo nibe o rubo
Nje ki ni Orunmila fi gba omon re lee lowo eleye
Ada orisa ni fi yo omo re lee lowo eleye
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Eye etu kan
- Abo adire kan
- Ada kan
- Eku
- Eja
- Epo
- Eko
- Obi
Ase — Ifa Spiritual Message
Ese — Yoruba Verse
Mo meyin mi siwon ni se ku pa awon agbalagba isegun
E ri le mi bawon yii, omode wonyii koje n sinmi
Adifa fun orunmila
Won ni odun yi ni odun ola baba
Pe ebo ni ki won o se
O gbebo nibe o rubo
Ero Ipo
Ero Offa
E wa bami jebutu ire gbogbo
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Eran ewure kan
- Epo
- Eko
- Obi
- Oti
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Isegun — Alchemist Formula
Yoruba
Explore Ifa
Osa Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Osameji. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Osa Ogbe, Osa Oyeku, Osa Iwori, Osa Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Osa Meji Odu.
