Feed Blog Circles Pages Dashboard
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Circle Create Page
Ose Meji

Ose Meji

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle 3 Languages Sacred Pattern
Listen
72 views Updated Oct 28, 2026 fafore.com/odu/ose-meji
Read in: English Yoruba Español Português Français Chinese Russian German Arabic
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa pe ire aiku fun eleyi, ifa pe ki eleyi o rubo emi re pe nkan kan ni jo onitohun laya yii, won ni ebo ni ko se kole ba di ire.

Ese — Yoruba Verse

Opole
Ni ko se muluku muluku
Adifa fun won lode ibadan
Nijo ti eranko finfin pawon lomo je
Ebo ni won ni ki won o se
Won gbebo ni be won rubo
Nje ibadan omesin ogo
Nile oluyole
Nibi ti eran fin fin tipa won lomo je.

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Akuko adire meta
  • Opolopo eko
  • Obi
  • Epo pupa
2
Ese Keji
Ese Keji

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa ni ki eleyi o rubo aiku nitori emi ree, ifa pe ebo ni ko se kio si mon lo bo ifa dara dara pelu eran oruko kan, emi re yio gun.

Ese — Yoruba Verse

Orofo
Awo won lo de ibadan
Lose fa fun won lo de ibadan
Ni jo ti won ku ni rogba rogba
Ti won ku ni rewe rewe
Bi eni ti won ji oun iku je
Ebo ni won ni ki won ose
Won gbebo ni be won rubo
Nje orofo ode
Awo ibadan
Arugbo awo agbo pate

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Eran oruko kan
  • Epo
  • Eko
  • Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa ni ohun pe ire gbogbo fun eleyi, ifa pe ki eleyi o mo ja, ki o si lo bo ifa daradara pelu eku eja abodire kan ki osi fi akuko adire kan rubo.

Ese — Yoruba Verse

Sese olonngo
Pirin ebiti
Adifa fun orunmila
Ni jo ti baba o mon sowo ijakadi kiri Kari aye
Ebo ni won ni kose
Ogbebo ni be o rubo
Nje toba dami malaje
Sese oloungo edu oleja
Toba dami mani ire gbogbo
Sese oloungo edu oleja

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Eku kan
  • Eja kan
  • Abodie kan
  • Akuko kan
  • Epo
  • Eko
  • Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ase — Ifa Spiritual Message

Ifa pe oun pe ire omo fun eleyi pe oju omo nipon eleyi, ifa ni ebo ni ko se kio le ba di olomon laye, ifa ni ko si lo bo orisa ati ifa pelu opolopo igbin.

Ese — Yoruba Verse

Opole ni ko se muluku muluku
Adifa fun won lode ibadan
Igbati won mu omi oju sogbere omo
Ebo ni won ni ki won o se
Won si gbebo ni be won rubo
Nje ibadan o
Omo ajegbin tan
Fi ikarahun ho ori imu

Ebo — Sacrifice (Etutu)

  • Igbin merindinlogun
  • Akuko adire kan
  • Epo
  • Eko
  • Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ao toju ewe aje ewe ominsin minsin gogoro ao wa lo mejeji papo ao wa fi se ekirin eran ewure merindinlogun je lepo ni yo ao se adura si ka toje obe naa daradara.

Isegun — Alchemist Formula

Yoruba

Ao toju ewe segunsete ao toju eran esin die, ao gun papo mo ara won ao wa po mon ose dudu, eni naa yo ma fi we ni a la le fun ojo meta.

Videos

Watch Ose Meji teachings on our channel.

Explore Ifa

Ose Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Ose Ogbe, Ose Oyeku, Ose Iwori, Ose Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ose Meji Odu.