Listen
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa ni ki eni to da Ifa Oyeku Meji o rubo aiku ki emi re o le gun. Ifa ni ebo ni kose dada.
Ese — Yoruba Verse
Oyesese labo loke
Omo araye se bi oju mo lomon
Adifafun baba yeku yeku
Ti won o mope o ni oyeku sapana
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe o rubo
Nje kini yio yeku nu lori awo
Eji oye Ifa ni yio yeku nu lori awo
Eji oye.
Omo araye se bi oju mo lomon
Adifafun baba yeku yeku
Ti won o mope o ni oyeku sapana
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe o rubo
Nje kini yio yeku nu lori awo
Eji oye Ifa ni yio yeku nu lori awo
Eji oye.
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Oruko kan
- Epo
- Eko
- Obi
- Owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa ni ki awon omo iya meta ki won o rubo, ki emi won ba le gun, ki won ofi aso dudu aso funfun ati aso pupa rubo.
Ese — Yoruba Verse
Opa gbogbo ni siwaju agbon nini
Ese mejeji ni jija de ona gborogan gborogan
Ati pe obi enu bobo aso kitipa abita wele
Adifa fun enlojo aso
Lojo ti won tode orun bo wale aye
Ebo ni won ni ki won ose
Won gbe ebo ni be won rubo
Nje kele loru o, Kele lo tu
Nje aso tomebo kiyo run
Toba toku je tan yio pada seyin
Aso tomebo ki yorun.
Ese mejeji ni jija de ona gborogan gborogan
Ati pe obi enu bobo aso kitipa abita wele
Adifa fun enlojo aso
Lojo ti won tode orun bo wale aye
Ebo ni won ni ki won ose
Won gbe ebo ni be won rubo
Nje kele loru o, Kele lo tu
Nje aso tomebo kiyo run
Toba toku je tan yio pada seyin
Aso tomebo ki yorun.
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Aso dudu
- Aso pupa
- Aso funfun
- Eran ewure kan
- Epo
- Eko
- Obi
3
Ese Keta
Ese Keta
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa ni ki eleyi o rubo kole ba laje pe oju aje nipon eleyi, ebo ni ko se kole ba laje oun.
Ese — Yoruba Verse
Atefa bere arobiunda
Apaju bere airobiunko
Sese ega eye ega sese
Adifafun laba nile o
Imo egba ni ile alake
Nigbati momi oju sogbere ire gbogbo
Ebo ni won ni kose
O gbe bo ni be o rubo
Nje kini yio sole doja fawo
Sese ega eye ega sese
Ifa ni yoo so le doja fawo
Ope bi, ko sai soja dile
Apaju bere airobiunko
Sese ega eye ega sese
Adifafun laba nile o
Imo egba ni ile alake
Nigbati momi oju sogbere ire gbogbo
Ebo ni won ni kose
O gbe bo ni be o rubo
Nje kini yio sole doja fawo
Sese ega eye ega sese
Ifa ni yoo so le doja fawo
Ope bi, ko sai soja dile
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Eku
- Eja
- Abodire
- Ewure
- Epo
- Eko
- Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ase — Ifa Spiritual Message
Ifa ni ki eleyin rubo ki ole bala ape oju aye nipon eleyin ki won osi se ifa be si kole ba lowo lowo.
Ese — Yoruba Verse
Won dafa sekeseke nile olufon
Moya mowo ranwon
Mo lugbin leyin kule orisa ojiyan
Moya mo wo ran awon aroni miini ke,
Sebi arara mi ki se ohun ati loku
Abuke ile irami mi mi kese ni
Adi loku gbonigboni sale sale
Adifa fun oyela ti n tode orun bowaye
Ebo won ni ko se nife
O sio gbebo nibe o rubo
Oyela bele gede tan naa ari naa
Oyela kari oun re gbogbo
Oyela belegede tan naa arinaa oyela
Moya mowo ranwon
Mo lugbin leyin kule orisa ojiyan
Moya mo wo ran awon aroni miini ke,
Sebi arara mi ki se ohun ati loku
Abuke ile irami mi mi kese ni
Adi loku gbonigboni sale sale
Adifa fun oyela ti n tode orun bowaye
Ebo won ni ko se nife
O sio gbebo nibe o rubo
Oyela bele gede tan naa ari naa
Oyela kari oun re gbogbo
Oyela belegede tan naa arinaa oyela
Ebo — Sacrifice (Etutu)
- Pepeye kan
- Epo
- Eko
- Obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
A o toju ina elegede ati ose dudu ao wa gun po ao ma fi we laro laro.
Isegun — Alchemist Formula
Yoruba
Ao toju ewe ayure pelu ewe apada ao wa jo po mo odidi atare kan a o wa fi sin gbere mokanlelogun si ori.
Explore Ifa
Oyeku Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Alchemist formulas (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Oyeku Ogbe, Oyeku Iwori, Oyeku Odi, Oyeku Irosun.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Oyeku Meji Odu.
